Chapter 25

الْمَقَامَةُ الْكرجية

11

يا قومِ لا ينبِئكُم عن فَقري. أصدقُ من عُريي أوان القُرِ.


English

O people, nothing tells you of my poverty more truthfully than my nakedness in the cold.

Yoruba

Ẹ̀yin ènìyàn, kò sí ohun tó sọ̀rọ̀ nípa ìyà mi dájú ju ìhòhò mi nígbà òtútù lọ.

12

فاعتَبِروا بِما بدا من ضري. باطِنَ حالي وخَفِيَ أمري.


English

So consider what appears of my suffering, the inner state of my condition and the hidden aspect of my affair.

Yoruba

Nítorí náà, ẹ wo ohun tí ó farahàn nípa ìyà mi, ìpò inú mi àti ohun tí ó farapamọ́ nípa ọ̀ràn mi.

13

وحاذِروا انقِلابَ سِلْمِ الدهرِ.


English

And beware the turning of the wheel of time.

Yoruba

Àti pé ẹ ṣọ́ra fún ìyípadà ayé.

14

فَإِنَّنِي كُنتُ نَبِيهَ القَدْرِ.


English

For I was of noble status.

Yoruba

Nítorí pé mo jẹ́ ẹni tí ó ní ipò gíga.

15

آوِي إِلَى وَفْرٍ وَحَدٍ يَفْرِي.


English

Seeking refuge in abundance and sharpness that cuts.

Yoruba

Mo ń wá ààbò nínú ọ̀pọ̀ àti idà tí ó lè gé.

16

تُفِيدُ صَفْرِي وَتُبِيدُ سَمْرِي.


English

My coin benefits, and my spear destroys.

Yoruba

Owó mí máa n ṣe àǹfààní, bẹẹ náà ni Ọkọ̀ mí ń ṣe iparun.

17

وَتَشْتَكِي كُومِي غَدَاةَ أَقْرِي.


English

And my loaded camels complain in the morning of my generosity.

Yoruba

Àti pé àwọn Ràkúnmí mi tí wọ́n ga sókè pẹlú ẹrù, ń ke ìrora ní òwúrọ̀ itọ́rẹ́ mí..

18

فَجَرَّدَ الدَّهْرُ سُيُوفَ الغَدْرِ.


English

Then time unsheathed the swords of treachery.

Yoruba

Nítorí náà, ayé bá yọ àwọn idà ọ̀dalẹ̀.

19

وَشَنَّ غَارَاتِ الرَّزَايَا الغُبْرِ.


English

And launched the raids of dusty calamities.

Yoruba

Àti pé ó bẹ̀rẹ̀ ìkógun àwọn ìjàmbá tí ó kún fún erùpẹ̀.

20

وَلَمْ يَزَلْ يَسْحَتُنِي وَيَبْرِي.


English

And it continued to erode and shave me.

Yoruba

Àti pé ó tẹ̀síwájú láti fọ̀ mi àti láti gé mi.

© , Qatru