Chapter 4

الْمَقَامَةُ الدِّمْيَاطِيَّةُ

1

أَخْبَرَ الْحَارِثُ بْنُ هَمَّامٍ قَالَ:


English

Al-Harith bin Hammam reported, saying:

Yoruba

Harisu ọmọ Hammam sọ̀rọ̀, ó wí pé:

2

ظَعَنْتُ إِلَى دِمْيَاطَ.


English

I journeyed to Damietta,

Yoruba

Mo ṣe ìrìnàjò lọ sí Damietta,

3

عَامَ هِيَاطٍ وَمِيَاطٍ.


English

In a year of commotion and turmoil..

Yoruba

Ní ọdún ìdàrúdàpọ̀ àti ìrúkèrúdò.

4

وَأَنَا يَوْمَئِذٍ مَرْمُوقُ الرَّخَاءِ.


English

And I was then looked upon with ease,

Yoruba

Nígbà náà, won ń wò mí pẹ̀lú ìrọ̀rùn,

5

مَوْمُوقُ الْإِخَاءِ.


English

Loved in brotherhood,

Yoruba

Olùfẹ́ nínú ìjẹ ọmọìyá,

6

أَسْحَبُ مَطَارِفَ الثَّرَاءِ.


English

Dragging the cloaks of wealth,

Yoruba

Mo ń wo aṣọ ọlá nile

7

وَأَجْتَلِي مَعَارِفَ السَّرَاءِ.


English

And beholding the signs of happiness.

Yoruba

Mo sì ń yo pelu awon apere ayọ̀.

8

فَرَافَقْتُ صَحْبًا قَدْ شَقُّوا عَصَا الشِّقَاقِ.


English

I accompanied companions who had split the staff of discord,

Yoruba

Mo bá àwọn ẹlẹgbẹ́ tí wọ́n ti run ọ̀pá ìjà,

9

وَارْتَضَعُوا أَفَاوِيقَ الْوِفَاقِ.


English

And suckled the udders of harmony.

Yoruba

Tí wọ́n sì mu ọmú ìṣọ̀kan.

10

حَتَّى لَاحُوا كَأَسْنَانِ الْمُشْطِ فِي الِاسْتِوَاءِ.


English

Until they appeared as the teeth of a comb in evenness,

Yoruba

Títí tí wọ́n fi dàbí eyín òòyà ní ìdọ̀gba,

© , Qatru