Chapter 12

الْمَقَامَةُ الدِّمَشْقِيَّةُ

1

حكى الحارثُ بن همّامٍ قال: شخصت من العِراقِ الى الغوطَةِ.


English

Al-Harith ibn Hammam said: I set out from Iraq to the Ghuta.

Yoruba

Hárìsù ọmọ Hammam sọ pé: Mo dide lọ láti ilẹ̀ Iraki lọ sí Guuta.

2

وأنا ذو جردٍ مربوطةٍ وجِدةٍ مغبوطَةٍ.


English

And I was a man of binded steeds and enviable fortune.

Yoruba

Ati pe emi jẹ ọkunrin ti oni awọn ẹṣin ti a dè ati ọrọ tí wọ́n jowú rẹ,

3

يلْهِيني خلو الذَّرعِ ويزدهيني حفولُ الضرعِ.


English

The absence of worry led me to entertainment, and the fullness of store led me to bragging,

Yoruba

Aìní wàhálà mú mi yọ, àti kíkún àpò mú mi ṣe ìgbéraga

4

فلما بلغتها بعد شق النفْسِ وإنضاء العنسِ.


English

When I reached it after a struggle of breath and the weariness of the mount.

Yoruba

Nígbà tí mo débẹ̀ lẹ́yìn wàhálà àti dídà mú ẹṣin.

5

ألفَيتها كما تصِفُها الألسن وفيها ما تشتهي الأنفُس وتلَذّ الأعينِ.


English

I found it as tongues describe, with all that the soul desires and the eyes delight in.

Yoruba

Mo bá a bí ẹnu ṣe ń ròyìn rẹ̀, pẹ̀lú gbogbo ohun tí ẹ̀mí ń fẹ́ àti ohun tí ojú ńfẹ́ràn.

6

فشكرت يد النوى وجريت طلَقاً مع الهَوى.


English

So I thanked the hand of travel and freely followed my desires.

Yoruba

Nítorí náà, mo dúpẹ́ fún ọwọ́ ìrìn-àjò, mo sì tẹ̀lé ìfẹ́ mi láìsí ìdènà.

7

وطفِقْت أفُض ختوم الشهواتِ وأجتني قُطوف اللّذّاتِ.


English

And I began to break the seals of desires and pick the fruits of pleasures.

Yoruba

Mo bẹ̀rẹ̀ sí já àwọn èdìdì ìfẹ́, mo sì já àwọn èso adùn jáde.

8

الى أن شرع سفر في الإعراقِ وقدِ استفَقْت من الإغْراقِ.


English

Until some travellers prepared to journey to Iraq, and I awakened from submergence.

Yoruba

Títí àwọn arìnrìn-àjò kan fi bẹ́ẹ̀rẹ sí lọ sí ìlú Iraki, tí mò sì tà jí kúrò nínú orun tó ti jìnà

9

فعادني عيد من تذْكارِ الوطَنِ والحَنينِ الى العطَنِ.


English

Then a festival of homeland memories and longing for familiar lands returned to me.

Yoruba

Nígbà yìí, ayẹyẹ ìrántí ilé àti ìfẹ́ sí ibi ìbí mi padà bọ̀ sí mi.

10

فقوضت خِيام الغيبةِ وأسرجت جواد الأوبةِ.


English

So I dismantled the tents of absence and saddled the steed of return.

Yoruba

Nítorí náà, mo rú ìtẹ̀ ìrìn-àjò, mo sì palẹmọ ẹṣin ìpadà mì.

© , Qatru