Chapter 12

الْمَقَامَةُ الدِّمَشْقِيَّةُ

21

فلما أنى انكِفاؤهم.


English

When their return was near.

Yoruba

Nígbà tí ipadà wọn wá tí yá

22

وقد برح له خفاؤهم.


English

And their concealment was revealed to him.

Yoruba

Tí àṣírí ọrọ wọn ti farahàn sí.

23

قال لهُم: يا قوم ليفرِخ كربكُم. وليأمن سِربكُم.


English

He said to them: "O people, let your worries rest, and let your path be secure."

Yoruba

Ó sọ fún wọn pé: "Èyin ènìyàn, ẹ jẹ́ kí ìbànújẹ́ yín dákẹ́, kí ọ̀nà yín sì jẹ́ àlàáfíà."

24

فسأخفُركُم بما يسرو روعكُم. ويبدو طوعكُم.


English

I will protect you with what pleases your hearts and ensures your compliance.

Yoruba

Máa ṣe ìtọ́jú yín pẹ̀lú ohun tó máa yọ ọkàn yín àti ohun tó máa dá yín loju.

25

قال الراوي: فاستطْلَعنا منه طِلْع الخِفارةِ.


English

The narrator said: So we inquired from him about the protection he offered.

Yoruba

Alágbékalẹ̀ sọ pé: Nítorí náà, a bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ nípa àbò tó ń ròyìn rẹ

26

وأسنينا له الجَعالَةَ عنِ السفارةِ.


English

And we promised him a reward for his mediation.

Yoruba

Àti pé a ṣe ìlérí fún un pẹ̀lú èrè fún nkan ìṣọ lọ́wọ́ rẹ̀.

27

فزعم أنها كلِمات لُقّنها في المَنامِ.


English

He claimed that these were words he was taught in a dream.

Yoruba

Ó sọ pé àwọn wònyí ni àwọn ọ̀rọ̀ tí wọ́n kọ́ ọ́ ní ojú àlá,

28

ليحترِس بها من كيدِ الأنامِ.


English

So that he may guard himself against the deceit of mankind.

Yoruba

Ki ó lè fí ṣọ ara rẹ̀ kúrò lọwọ ète àwọn èèyàn,

29

فجعلَ بعضنا يومِض الى بعضٍ.


English

So some of us signaled to each other.

Yoruba

Nígbà náà, àwọn kan nínú wa bẹ̀rẹ̀ sí í ṣẹjú sí ará wọn.

30

ويقلّب طرفَيهِ بين لحْظٍ وغضٍ.


English

And shifting gaze between glancing and lowering it.

Yoruba

Ó ń yí ojú rẹ̀ láàárín gbígbé ojú sókè àti ilẹ̀

© , Qatru