Chapter 12

الْمَقَامَةُ الدِّمَشْقِيَّةُ

91

وخُضتُ السيولَ. ورضتُ الخيولَ. لجر ذُيولِ الصبى والمرح.


English

I have waded through floods and trained horses to experience the remnants of youth and delight.

Yoruba

Mo ti kọjá nínú omi àgbàrá, mo sì ti gbé ẹṣin láti gbádùn àbọ̀ ìgbà ewé mi àti ìtura.

92

ومِطتُ الوقار. وبعتُ العقار. لحسوِ العقارِ ورشْفِ القدح.


English

I have abandoned dignity and sold properties to indulge in wine and sip from the cup.

Yoruba

Mo ti fi àpọnle sílẹ̀, mo sì tí tà ohun-ini láti fi tẹ̀ lé mímu ọtí àti ife rẹ

93

ولولا الطِّماح الى شُربِ راحٍ. لما كان باح فَمي بالملَح.


English

Were it not for the yearning to drink wine, my mouth would not have spoken a word of cheer.

Yoruba

Bí kò bá ti jẹ́ ìfẹ́ mímu ọtí, ẹnu mi kì yóò ti sọ ọ̀rọ̀ ìwúrí kan kan.

94

ولا كان ساقَ دهائي الرفاقَ. لأرضِ العِراقِ بحملِ السبح.


English

Nor would my cunning have guided my companions to the land of Iraq while bearing rosaries.

Yoruba

Ète mi kò bà má dárí àwọn ọ̀rẹ́ mi sí ilẹ̀ Iràkì pẹ̀lú àwọn isun tẹsùba lọwọ

95

فلا تغضبن ولا تصخَبن. ولا تعتُبن فعذْري وضح.


English

Therefore, do not be angry or raise your voice, and do not blame me, for my excuse is clear.

Yoruba

Torí náà, ẹ má ṣe bínú tàbí gbé ohùn yín soke, ẹ má sì bù mi, torí àwáwi mí hàn kedere.

96

ولا تعجبن لشيخٍ أبن. بمغْنًى أغَن ودن طفَح.


English

And do not be surprised at an elder who indulges in a vibrant place and relishes in its abundance.

Yoruba

Ẹ má ṣe jẹ kí o yàà yin lẹnu nígbà tí àgbàlagbà kan bá ń gbádùn ní ibi tí ó kún fún igbadun, ó sì ń gbádùn nínú àwọn nkan ìdárayá

97

فإن المدام تُقوي العِظام. وتَشْفي السقام وتنْفي التّرح.


English

For indeed, wine strengthens the bones, heals ailments, and dispels sorrow.

Yoruba

Torí pé, ọtí ń fún egungun ni ágbára, ó ń ṣe ìwòsàn ara, ó sì ń lé ìbànújẹ́ jáde kúrò ní ara ẹni.

98

وأصفى السرورِ. إذا ما الوقور أماطَ ستور الحيا واطّرح.


English

The purest form of joy is when the dignified removes the veil of modesty and relinquishes restraint.

Yoruba

Ayọ̀ mimọ julọ ní ìgbátí ọmọlúwàbí ba gbé àṣọ ìtìjú kúrò lójú, tí ó sì Júù sílẹ̀

99

وأحلى الغَرام إذا المستهام. أزالَ اكتِتام الهوى وافتضح.


English

The sweetest love is when the passionate one unveils hidden desires and confesses openly.

Yoruba

Ifẹ́ tó dára jùlọ ni nígbà tí ẹni tí ololufe bá ṣìnà fún ìfẹ́ tio sì ṣe ìbàjẹ́

100

فبح بهواك وبرد حشاك. فزنْد أساك بهِ قد قدح.


English

So express your love, calm your heart, for the firestaff of your suffering has ignited a spark within you.

Yoruba

Torí náà, fi ifẹ́ rẹ hàn, kí èrò inú rẹ lè tú sílẹ̀, nítorí pé igi-ìṣana ìbànújẹ́ rẹ tí ṣana

© , Qatru