He said: I do not wish to reveal myself, but I will give a clue: I am the wonder of the ages and the marvel of nations.
Ó sọ pé: Kò wunmi làti ṣe àlàyé ara mí, ṣùgbọ́n má pa òwe; Èmi ni ìyàlẹ́nu ayé àti ìyàlẹ́nu àwọn orílẹ̀-èdè.
And I am the one who maneuvered among the Arabs and the non-Arabs.
Ẹ̀mi ni eléte tí ó ṣe ète láàrín àwọn ará Arabu àti àwọn tí kì í ṣe ará Arabu.
But I am the son of need, crushed by time and swallowed.
Ṣùgbọ́n ẹ̀mí ni ọmọ òníbùkátà, tí àkókò ti fọ́, tí ó sì ti jẹ.
And the father of children who appeared like meat on a skewer.
Àti baba àwọn ọmọ tí ó hàn bí ẹran lórí ìgì.
And the brother of the needy, who, if he maneuvers, is not blamed.
Àti arákùnrin aláìní, tí bí ó bá ṣe ẹ̀tan, kò ní rí èébú.
The narrator said: Then I knew that he was Abu Zayd, the one with doubts and flaws.
Olùsọ̀rọ̀ sọ pé: Nígbà náà ni mo mọ̀ pé Abu Seidu ni, ẹni tí ó ní iyèméjì àti àbùkù.
And his face darkened by gray hair.
Àti ojú rẹ̀ tí ó dúdú nítorí irun fúnfun.
And I was displeased by the magnitude of his rebellion.
mo bínú nípa títóbi ìwà búburú rẹ
And the ugliness of his arrogance.
Àti Áìdara ìgbéraga rẹ̀.
So I said to him with a tongue of pride and the confidence of knowledge:
Nítorí náà, mo sọ fún un pẹ̀lú ahọ́n ìgbéraga àti ìgboyà ìmọ̀: