Chapter 11

الْمَقَامَةُ السَّاوِيَّةُ

61

الى أن ينخَر العود.


English

Until the wood of the coffin bent

Yoruba

Títí àwọn igi pósí fi tẹ

62

ويمسي العظم قد رم.


English

And the bones become dust.

Yoruba

Àwọn egungun náà di eruku.

63

ومن بعد فلا بد.


English

And thereafter, it is certain.

Yoruba

Ìgbà náà, kò sí ibuyẹsi

64

من العرضِ إذا اعتُد.


English

From the review of souls, if it had been laid

Yoruba

Láti se ìwádìí nípa ẹmi, tí won ba ti pálẹmọ

65

صِراطٌ جسره مد.


English

The Sirat whose bridge is extended.

Yoruba

Òkè Asirati, ti ọ̀nà rẹ gùn gan-an

66

على النارِ لمن أم.


English

Over the fire for those who come.

Yoruba

Lórí iná fún àwọn tó wá.

67

فكم من مرشدٍ ضلّ.


English

How many guides have strayed.

Yoruba

Ọpọ ẹlẹ́kọ̀, ní wọn tí ṣègbé!

68

ومن ذي عِزةٍ ذَلّ.


English

And most of the mighties has been humbled.

Yoruba

Ọpọ ọlọlá ní wọn ti yẹpẹrẹ

69

وكم من عالِمٍ زلّ.


English

And how many scholars have slipped.

Yoruba

Ọpọ ọ̀nìmọ́ ni ó ti ṣe aṣisẹ̀.

70

وقال الخطْب قد طم.


English

And said: the calamity has overtaken.

Yoruba

O sọrọ pé: Àjálù tí dé

© , Qatru