And his deceit.
Àti ẹtanjẹ rẹ̀.
I said to him: How long, O Abu Zaid.
Mo sọ fún un pé: Dìgbà wo, Abu Seidu
Your tricks in deceit.
Àwọn ẹ̀tan rẹ nínú ète
To make the prey come to you.
Láti jẹ́ kí ẹran wọ pakute rẹ
And you do not care about who abused
O sì náání èèyàn tó bù ọ
He replied without shame.
Ó dáhùn láìní ìtìjú
And without hesitation.
Àti láìsí iyèméjì
He said: Be insightful and leave blame.
Ó sọ pé: Jé kí ó ye ọ kí o sì fi èébú sílẹ̀.
Tell me, do you see today.
Sọ fún mi, ṣé o rí oún náà lónìí.
A young man who does not outshine the people.
Ọmọde tí kò ní gòkè ju ènìyàn lọ.