Chapter 23

الْمَقَامَةُ الشِّعرية

71

فقال: إني مولَع من أنواعِ البلاغَةِ بالتجنيس.ِ وأراه لها كالرئيس.ِ


English

He said: I am passionate about the types of eloquence, especially paronomasia. I see it as its leader.

Yoruba

Ó sọ pé: Mo nífẹ̀ẹ́ sí àwọn oríṣiríṣi ẹ̀wà ìṣàlàyé, pàápàá jùlọ ẹ̀wà gbólóhùn kan pẹlú orísirísi ìtumọ̀. Mo rí i bí olórí rẹ̀.

72

فانظِما الآنَ عشرةَ أبياتٍ تلحِمانِها بوشيِه.ِ


English

Now both of you to compose ten verses, weaving them with its beauty.

Yoruba

Bayìí kí ẹ̀yín méjèèjì kọ ẹsẹ mẹ́wàá, tí wọ́n ń hun wọn pọ̀ pẹ̀lú ẹwà rẹ̀.

73

وترصعانِها بحلْيه.ِ وضمناها شرح حالي.


English

And adorn them with its ornaments, including explanation of my state.

Yoruba

Àti pé, kí ẹ̀ ṣe wọn lọ́ṣọ́ pẹ̀lú àwọn ohun ẹ̀ṣọ̀, kí ẹ̀ sì kó alààyè ìpò mi sí.

74

مع إلْفٍ لي بديعِ الصفَة.ِ ألمَى الشفَة.ِ مليحِ التثَني.


English

With a companion of exquisite qualities, dark-lipped, graceful in movement.

Yoruba

Pẹ̀lú ọ̀rẹ́ kan tó dára ní ìròyìn, ẹlẹ́nu dúdú, tí ó je alaanu nibi ibasepọ.

75

كثيرِ التيهِ والتجني. مغرى بتناسي العهد.ِ


English

Much arrogance and cruelty, infatuated with forgetting promises.

Yoruba

Púpọ̀ nínú ìgbéraga àti ìkà, tí ó nífẹ̀ẹ́ sí gbàgbé ìlérí.

76

وإطالَةِ الصد. وإخلافِ الوعد.ِ وأنا له كالعبد.ِ


English

Prolonging estrangement and breaking promises, and I am like a servant to him.

Yoruba

Ìgbékalẹ̀ ìyàtọ̀ àti ìparun ìlérí, èmi sì dàbí ẹrú fún un.

77

قال: فبرز الشيخ مجلّياً. وتلاه الفَتى مصلّياً.


English

He said: The sheikh appeared, illuminating, followed by the young man like the second in the race.

Yoruba

Ó sọ pé: Alàgbà náà farahàn, tí ó ń tan ìmọ́lẹ̀, tí ọ̀dọ́kùnrin náà tẹ̀lé e, bi ẹ̀ní kejì nínú pápá ìdíje.

78

وتجاريا بيتاً فبيتاً على هذا النسق.ِ


English

And they competed verse by verse in this manner.

Yoruba

Wọ́n sì di je kikọ́ ẹsẹ lórí ẹsẹ ní irú èyí.

79

الى أن كملَ نظْم الأبياتِ واتسق.


English

Until the composition of the verses was completed and harmonized.

Yoruba

Títí tí àkọsílẹ̀ àwọn ẹsẹ náà fi pé tí ó sì ṣọ̀kan.

80

وأحوى حوى رِقّي برِقّةِ ثغْرِهِ.


English

The Old Man: "And a dark one captured my affection with the tenderness of her smile".

Yoruba

Baba náà: "Àti ẹni dúdú kan tí ó gba ìfẹ́ mi pẹ̀lú ìfẹ́ rẹ̀."

© , Qatru