English: Al-Harith bin Hammam reported, saying:
Yoruba: Harisu ọmọ Hammam sọ̀rọ̀, ó wí pé:
English: I journeyed to Damietta,
Yoruba: Mo ṣe ìrìnàjò lọ sí Damietta,
English: In a year of commotion and turmoil..
Yoruba: Ní ọdún ìdàrúdàpọ̀ àti ìrúkèrúdò.
English: And I was then looked upon with ease,
Yoruba: Nígbà náà, won ń wò mí pẹ̀lú ìrọ̀rùn,
English: Loved in brotherhood,
Yoruba: Olùfẹ́ nínú ìjẹ ọmọìyá,
English: Dragging the cloaks of wealth,
Yoruba: Mo ń wo aṣọ ọlá nile
English: And beholding the signs of happiness.
Yoruba: Mo sì ń yo pelu awon apere ayọ̀.
English: I accompanied companions who had split the staff of discord,
Yoruba: Mo bá àwọn ẹlẹgbẹ́ tí wọ́n ti run ọ̀pá ìjà,
English: And suckled the udders of harmony.
Yoruba: Tí wọ́n sì mu ọmú ìṣọ̀kan.
English: Until they appeared as the teeth of a comb in evenness,
Yoruba: Títí tí wọ́n fi dàbí eyín òòyà ní ìdọ̀gba,