English: And I love the close friend,
Yoruba: Mo sì fẹ́ràn ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,
English: Even if he makes me drink boiling water.
Yoruba: Bí ó tilẹ̀ mú mi mu omi gbígbóná.
English: And I prefer the compassionate
Yoruba: Mo sì fẹ́ràn aláàánú
English: Over the brother
Yoruba: Ju omoiyami lọ
English: And I am loyal to the companion
Yoruba: Mo sì ṣe olóòótọ́ sí ọ̀rẹ́
English: Even if not reciprocated equally
Yoruba: Bí kò tilẹ̀ san padà bákannáà
English: And I consider abundant
Yoruba: Mo sì má n pese púpọ̀
English: For the guest
Yoruba: Fún àlejò
English: And I overwhelm the colleague
Yoruba: Mo sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ fún ẹlẹgbẹ́
English: With kindness
Yoruba: Pẹ̀lú inú rere