And his tears are about to flow.
Omijé rẹ̀ sì tí fẹ ṣàn.
He disliked to let them flow.
Ó kórìíra láti jẹ́ kí wọ́n ṣàn.
And he could not hold them back.
kò si lè dá wọ́n dúró.
So he cut short his sweet recitation.
Nítorí náà, ó ge orin rẹ̀ tí ó dùn kúrò.