English: Until they were overwhelmed with gifts.
Yoruba: Títí tí ẹ̀bùn fi bò wọ́n mọ́lẹ̀.
English: And were taken as close friends.
Yoruba: A sì mú wọn bí ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́.
English: We were at a resting place from which we could see the buildings of villages.
Yoruba: A wà ní ibi ìsinmi kan tí a ti lè rí àwọn ilé ìlú náà.
English: And discern the fires of hospitality.
Yoruba: A sì ń rí iná àlejò.
English: When Abu Zayd saw his purse was full.
Yoruba: Nígbà tí Abu Seidu rí i pé àpò rẹ̀ ti kún.
English: And his misery had cleared.
Yoruba: Tí òsì rẹ̀ sì ti kúrò.
English: He said to me: My body has become dirty.
Yoruba: Ó sọ fún mi pé: Ara mi ti dọtí.
English: And my grime has been firm
Yoruba: Èérí sì ti lẹ̀ mọ́ mi.
English: Do you permit me to go to a village to bathe?
Yoruba: Ṣé o yóò fún mi láààyè láti lọ sí ìlú kan láti wẹ̀?
English: And accomplish this important matter?
Yoruba: Kí n sì ṣe ohun pàtàkì yìí?