Chapter 17

الْمَقَامَةُ القهقرية

21

وإنْ طلعت من مغرِبِها. فَيا لعجبِها!


English

And if it rises from its west, then how astonishing it is!

Yoruba

Tí ó bá sì jáde láti ìwọ̀-òòrùn rẹ̀, báwo ni ìyàlénu rẹ̀ ṣe jẹ́ tó bẹẹ́!

22

قال: فكأنّ القوم رموا بالصمات.ِ أو حقّت عليهِم كلمةُ الإنصات.ِ


English

He said: It was as if the people were struck with silence, or the command of listening was made binding upon them.

Yoruba

Ó sọ pé: Ó dàbí ẹni pé àwọn ènìyàn fi ẹnu pa mọ́ tàbí òfin láti fetí sílè ti jẹ́ òranyàn lórí wọn

23

فما نبس منهم إنسانٌ. ولا فاه لأحدِهِم لِسانٌ.


English

No one among them uttered a word, and no one's tongue moved.

Yoruba

Kò sí ẹnikẹ́ni nínú wọn tó sọ ohunkóhun, kò sí ẹnikẹ́ni tí ahọ́n rẹ̀ yí.

24

فحين رآهم بكْماً كالأنعام.ِ وصموتاً كالأصنام.ِ


English

When he saw them mute like cattle and silent like idols,

Yoruba

Nígbà tí ó rí wọn bí ẹni tí kò lè sọrọ bí ẹran ọ̀sìn, tí wọ́n sì ṣe ìdákẹ́jẹ́ bí òrìṣà.

25

قال لهُم: قد أجلتكُم أجلَ العِدة.ِ وأرخيت لكُم طِولَ المُدة.


English

He said to them: I have given you ample time and extended the period for you.

Yoruba

Ó sọ fún wọn pé: Mo ti fún yín ní àkókò púpọ̀, mo sì fi àkókò kún fún yín.

26

ثم هاهنا مجمع الشمل.ِ وموقِف الفصل.ِ


English

And here is the place of gathering and the moment of decision.

Yoruba

Ayeyi náà ni ibi ipàdé àti àkókò ìdájọ́.

27

فإنْ سمحت خواطركُم مدحنا. وإنْ صلدت زِنادكُم قدحنا.


English

If your thoughts permit, we will praise; if your firing log resist, we will strike!.

Yoruba

Tí èrò yín bá gba, àwa yóò yin yín; ṣùgbọ́n tí òkúta iná yín bá kọ, a wá yóò ṣaná.

28

فقالوا له: واللهِ ما لَنا في لُجةِ هذا البحرِ مسبح. ولا في ساحِلِهِ مسرح.


English

They said to him: By God, we have neither the strength to swim in the depths of this sea nor to walk along its shore.

Yoruba

Wọ́n sọ fún un pé: ni orúkọ Olúwa, kò sí agbára wa láti wẹ ní inú òkun yìí tàbí láti rìn lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀gbẹ̀ rẹ̀.

29

فأرِح أفكارنا من الكد. وهنئِ العطيةَ بالنقْد.ِ


English

So relieve our thoughts from toil, and let the gift be exchanged for something tangible.

Yoruba

Nítorí náà yọ àwọn ero wa lọwọ ìdààmú, ki ó sì jẹ ki a paarọ ẹbun náà fun ohùn ojúlówó.

30

واتخِذْنا إخواناً يثِبونَ إذا وثَبت. ويثيبونَ متى استثَبت.


English

And take us as brothers who leap when you leap and reward when you ask for a reward.

Yoruba

Ki o si mu wa bi àwọn ọmọ ìyá ti o nfò nigbati o ba nfò ati wọn yóò fún ọ ní ere nigbati o ba beere fun ere.

© , Qatru