Or compose a virgin epistle
Tàbí kọ ìwé àkọ́kọ́ tí kò tí ì sí rí
And that the most eloquent of writers of this time
Àti pé àwọn onímọ̀ akọ̀wé àsìkò yìí
Those who mastered the reins of expression
Àwọn tó mọ ìdí ọ̀rọ̀ sísọ dáadáa
Are like dependents upon the ancients
Wọ́n dàbí ẹni tó ń gbẹ́kẹ̀lé àwọn àtijọ́
Even if they possessed the eloquence of Sahban Wa'il
Bí wọ́n tilẹ̀ ní ọgbọ́n ọ̀rọ̀ sísọ bí Sahban Wa'il
And in the assembly was a middle-aged man sitting on the edge
Nínú ìpàdé náà, ọkùnrin àgbàlagbà kan jókòó ní ẹ̀gbẹ́
At the standing place of the entourage
Níbi tí àwọn ẹrú jókòó sí
And whenever the people went too far in their discourse
Nígbàkúgbà tí àwọn ènìyàn bá ti kọjá àlà nínú ọ̀rọ̀ wọn
And spread out their dates and elevated talks from their strings
Tí wọ́n sì tàn ọ̀rọ̀ eyi tó wù yí àti èyí tí kó wù yí wọn jáde nínú ọpọlọ wọn
The squinting of his eyes would indicate
Ìfojúsọ́nà rẹ̀ á máa fihàn