English: Inherited from them due to the antiquity of their origins
Yoruba: Tí a jogún lọ́wọ́ wọn nítorí pé wọ́n ti pẹ́
English: Not for the precedence of the source over the derivative?
Yoruba: Kì í ṣe tí ìṣáájú débi ọgbọ́ǹ ọrọ̀ ju èyí tó jáde wá lọ?
English: And indeed I know now one who when he composes
Yoruba: Nítòótọ́ mo mọ ẹnìkan báyìí tí ó bá kọ ǹkan
English: He embellishes
Yoruba: Ó ń ṣe é lọ́ṣọ́
English: And when he expresses
Yoruba: Tí ó bá sì sọ̀rọ̀
English: He enlightens
Yoruba: Ó ń ṣe àlàyé
English: And if he elaborates
Yoruba: Tí ó bá sì sọ púpọ̀
English: He amazes
Yoruba: Ó ń ya ní lẹ́nu
English: And when he is concise
Yoruba: Tí ó bá sì sọ díẹ̀
English: He incapacitates
Yoruba: Ó ń mú kí ẹnu ó yà wọ́n