English: Sometimes she trots like a strong horse.
Yoruba: Nígbà mìíràn ó máa ń sáré bí ẹṣin alágbára.
English: And at times she sleeps in the cradle.
Yoruba: Ní àwọn ìgbà mìíràn ó máa ń sùn nínú àpótí ọmọ.
English: And she feels cold in July.
Yoruba: Ó sì máa ń ní òtútù ní oṣù Keje.
English: Possessing intellect and restraint.
Yoruba: Ó ní ọgbọ́n àti ìkóra-ẹni-níjàánu.
English: And sharpness and a spearhead.
Yoruba: Àti mímú àti orí ọ̀kọ̀.
English: And a palm with fingers.
Yoruba: Àti àtẹ́lẹwọ́ pẹ̀lú ìka.
English: And a mouth without teeth.
Yoruba: Àti ẹnu láìsí eyín.
English: She stings with a snake like tongue.
Yoruba: Ó máa ń ta pẹ̀lú ahọ́n ejò
English: And she struts in a training robe.
Yoruba: Ó sì máa ń rìn arinyan nínú aṣọ ìṣẹ
English: And she is revealed in black and white.
Yoruba: A sì máa ń fihàn nínú dúdú àti funfun.