الْمَقَامَةُ الرَّحْبِيَّةُ

عَرَبِيَّة : فَنَقَدَهُ الْوَالِي عِشْرِينَ.

English: So the governor paid him twenty.

Yoruba: Nítorí náà gómìnà náà san ogún fún un.

عَرَبِيَّة : وَوَزَّعَ عَلَى وَزَعَتِهِ تَكْمِلَةَ خَمْسِينَ.

English: And distributed among his guards the completion of fifty.

Yoruba: Ó sì pín láàrín àwọn olùṣọ́ rẹ̀ ìpín tó kù nínú àádọ́ta.

عَرَبِيَّة : وَرَقَّ ثَوْبُ الْأَصِيلِ.

English: And the cloth of the evening is becoming low

Yoruba: Aṣọ òru tí ń fẹlẹ,

عَرَبِيَّة : وَانْقَطَعَ لِأَجْلِهِ صَوْبُ التَّحْصِيلِ.

English: And for his sake, the path of achievement was cut off.

Yoruba: Àti pé nítorí rẹ̀, a gé ọ̀nà ìgbà owó jọ kúrò.

عَرَبِيَّة : فَقَالَ: خُذْ مَا رَاجَ.

English: So he said: Take what is in available

Yoruba: Nítorí náà ó sọ pé: Mú ohun tí ó tí wa

عَرَبِيَّة : وَدَعْ عَنْكَ اللَّجَاجَ.

English: And leave behind the obstinacy.

Yoruba: Kí o sì fi agídí sílẹ̀.

عَرَبِيَّة : وَعَلَيَّ فِي غَدٍ أَنْ أَتَوَصَّلَ.

English: And tomorrow, it's upon me to arrange.

Yoruba: Àti lọ́la, ó jẹ́ ojúṣe mi láti ṣe ètò.

عَرَبِيَّة : إِلَى أَنْ يَنِضَّ لَكَ الْبَاقِي وَيَتَحَصَّلَ.

English: Until the remainder is liquefied for you and obtained.

Yoruba: Títí tí ìyókù yóò fi jáde fún ọ àti kí a gbà á.

عَرَبِيَّة : فَقَالَ الشَّيْخُ: أَقْبَلُ مِنْكَ عَلَى أَنْ أُلَازِمَهُ لَيْلَتِي.

English: The old man said: I accept from you on condition that I stay with him tonight.

Yoruba: Àgbàlagbà náà sọ pé: Mo gbà lọ́wọ́ rẹ pẹ̀lú ìdí pé èmi yóò dúró pẹ̀lú rẹ̀ lálẹ́ yìí.

عَرَبِيَّة : وَيَرْعَاهُ إِنْسَانُ مُقْلَتِي.

English: And the pupil of my eye will watch over him.

Yoruba: Àti pé ọmọ ojú mi yóò ṣọ́ ọ.

Use the pagination below to see more verses
No forum available for this book yet
© , Qatru