English: Lower your gaze to find peace from longing.
Yoruba: Rẹ ojú rẹ̀ sì lẹ kí ó bá lè ní ìsinmi lọ́wọ́ ifẹ
English: For it clothes you in the garb of humiliation and shame.
Yoruba: Nítorí pé ó wọ aṣọ ìyẹpẹrẹ àti àbùkù.
English: The man's trial is following his own desires.
Yoruba: Adánwò ọmọniyan ni tí tẹle ìfẹ́ inú
English: Seed of desires is an insatiable eye.
Yoruba: Èso ifẹ́ ní ojúkòkòrò
English: The narrator said: I tore his letter into tiny pieces.
Yoruba: Olugba ẹgbawa sọ̀rọ̀: Mo ya lẹ́tà yẹlẹ yẹlẹ
English: And I did not care whether he blamed or excused me.
Yoruba: Ẹ mí kò sí wádìí pé bóyá wọn yóò bù mí tàbí f'ori jì mí.