English: You have gained from it understanding and resolve.
Yoruba: O ti rí ìmòye àti ìdánùṣọ́ lára rẹ̀.
English: The wise and astute seek these.
Yoruba: Ẹni tó ní làákàyè àti ọlọ́gbọ́n máa ń wá àwọn wọ̀nyí.
English: So, resist desires thereafter.
Yoruba: Nígbà yìí, gbìyànjú láti dá èrò kúrò.
English: And know that hunting gazelles is not easy.
Yoruba: Máa mọ̀ pé di dẹdẹ ẹtu kò rọrùn.
English: Not every bird falls into the trap.
Yoruba: Kì í ṣe gbogbo ẹyẹ ló ń wọ pakute
English: Even if it is surrounded by silver.
Yoruba: Kódà tí wọ́n bá fi fàdákà yìí ka
English: And how many sought to hunt but were themselves caught.
Yoruba: Mélòó Mélòó èèyàn ló gbìyànjú láti dẹdẹ ló bá kosi pakute ẹlòmíràn
English: And met not but pair shoes of Hunayn.
Yoruba: Àti ẹni tí kò pàdé nkankan yà tọ sí ẹsẹ méjì bàtà Hunain
English: Be wise and do not follow every flash of lightning.
Yoruba: Máa ṣọra, má ṣe tẹ lé gbogbo etimọ
English: For some lightning contains deadly strikes.
Yoruba: Nítorí ọpọ etimọ mìíràn ni aráìkú ń bẹ nínú rẹ