English: Al-Harith bin Hammam narrated, saying:
Yoruba: Harisu ọmọ Hammam sọ̀rọ̀, ó wí pé:
English: When I mounted the hump of exile
Yoruba: Nígbà tí mo joko sorí ràkúnmí ìrìn ajo
English: And poverty distanced me from my peers
Yoruba: Tí òṣì sì mumi jìnnà sí àwọn ẹlẹgbẹ́ mi
English: The vicissitudes of time tossed me
Yoruba: Àwọn ìyípadà àkókò ju mi
English: To Sana'a of Yemen
Yoruba: Sí Sana'a ní Yemen
English: I entered it with an empty sack
Yoruba: Mo wọ ilu naa pẹ̀lú àpò òfìfo
English: Clearly destitute
Yoruba: Ní irisi aláìní
English: Possessing no provisions
Yoruba: Mi ò ní ohun èlò
English: And finding not in my bag a morsel
Yoruba: Bẹ́ẹ̀ ni n kò rí oúnjẹ kékeré kan nínú àpò mi
English: So I began to roam its streets like one bewildered
Yoruba: Nígbà náà ni mo bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn káàkiri àwọn òpópóna rẹ̀ bí ẹni tí orí ń yí