Chapter 26

الْمَقَامَةُ الرقطاء

71

قال:


English

He said:

Yoruba

Ó sọ pé:

72

لا تطْمع في الإنظار.ِ واحتِجانِ النضار.ِ


English

Do not hope for delay or the hoarding of gold.

Yoruba

Má ṣe retí ìdádúró tàbí ìkójọpọ̀ wúrà.

73

فوحقّك ما ترى مسالِك الخَلاص.ِ أو تريني سبائِك الخِلاصِ!


English

By your right, you will not see paths of salvation or show me the ingots of deliverance!

Yoruba

Nípà ẹ̀tọ́ rẹ, ìwọ kò ní rí àwọn ọ̀nà ìgbàlà tàbí fi àwọn ìdí ìgbàlà hàn mí!

74

فلما رأيت احتِداد لَددِه.ِ وأنْ لا مناص لي من يدِه.ِ


English

When I saw his stubbornness and that there was no escape from his hand.

Yoruba

Nígbà tí mo rí ìwà ìdúró rẹ̀ àti pé kò sí ìbálẹ̀ láti ọwọ́ rẹ̀.

75

شاغَبته. ثمّ واثبته.


English

I quarreled with him, then I subdued him.

Yoruba

Mo bá a jà, lẹ́yìn náà mo lù u.

76

ليرافِعني الى والي الجَرائِم.ِ لا الى الحاكِمِ في المظالم.ِ


English

To take me to the governor of crimes, not to the judge of injustices.

Yoruba

Láti mú mi lọ sí gomina àwọn ẹ̀ṣẹ̀, kì í ṣe sí adájọ́ àwọn àbòsí.

77

لِما كان بلَغني من إفْضالِ الوالي وفضلِه.ِ وتشددِ القاضي وبخلِه.ِ


English

Because I had heard of the governor's generosity and virtue, and the judge's strictness and stinginess.

Yoruba

Nítorí mo ti gbọ́ nípa ìfẹ́ àti ìwà rere Gomina, àti ìwà ile koko àti ahún Adájọ́ náà.

78

فلما حضرنا باب أميرِ طوس. آنست أن لا بأس ولا بوس.


English

When we arrived at the gate of the Emir of Tus, I felt no fear or distress.

Yoruba

Nígbà tí a dé ẹnu-ọ̀nà Ọba Tusi, mo kò ní ìbẹ̀rù tàbí ìbànújẹ́.

79

فاستدعيت دواةً وبيضاء.َ وأنشأت رِسالةً رقْطاء.َ


English

I called for ink and paper, and wrote a speckled letter.

Yoruba

Mo bèèrè fún inki (Tàdáwà) àti ìwé, mo sì kọ lẹ́tà tí alúfábẹ́ẹ̀tì rẹ tó ní àmì-ìdámọ̀ yóò tẹle èyí tí kò ní àmì-ìdámọ̀.

80

وهي: أخلاق سيدِنا تحب. وبعقْوتِهِ يلَب.


English

It read: Our master's manners are beloved, and at his dooryard people stayed.

Yoruba

Ó kà pé: Ìwà Aṣíwájú wa jẹ́ ìfẹ́, àgbàlá rẹ ibùdó àwọn èèyàn

© , Qatru