Chapter 24

الْمَقَامَةُ الْقطيعية

111

واستسلَمت تمائِمنا لسِحرِه.


English

And our charms surrendered to its magic.

Yoruba

Ti àwọn àṣírí paró wa fi ara wọn lẹ fún ìdán rẹ̀.

112

عدلْنا منِ استِثْقالِ الرؤيةِ له الى استِنزالِ الروايةِ عنه.


English

We shifted from the burden of seeing it to the ease of narrating it.

Yoruba

A yí padà láti ìnira rírí rẹ̀ sí ìròyìn rẹ̀.

113

ومِن بغيِ التبرمِ بهِ الى ابتِغاء التعلّمِ منه.


English

And from the evil of being offended with him, to the pursuit of learning from him.

Yoruba

Ati kúrò nínú aburú bìbínú wá sí làti ọdọ rẹ̀ sí ìfẹ́ kikọ́ ẹ̀kọ́ rẹ̀.

114

فقال: والذي نزلَ النحو في الكَلام.


English

He said: By Him who sent down grammar into speech.

Yoruba

Ó sọ pé: Nípa Ẹni tó sọ̀ ìmọ Gírámà kalẹ sínú ọ̀rọ̀.

115

منزلَةَ المِلْحِ في الطّعام.


English

Like salt in food.

Yoruba

Bí iyọ̀ nínú oúnjẹ.

116

وحجبه عن بصائِرِ الطّغام.


English

And concealed it from the insights of the ignorant.

Yoruba

ó sì fi í pamọ́ kúrò nínú ìmòye àwọn òmùgọ̀.

117

لا أنلْتكُم مراماً.


English

I will not grant you your desire.

Yoruba

Èmi kì yóò fún yín ní ìfẹ́ yín.

118

ولا شفيت لكُم غَراماً.


English

Nor will I satisfy your longing.

Yoruba

Ati èmi kì yóò mú ìfẹ́ yín ṣẹ.

119

أو تخولَني كلُّ يدٍ.


English

Until every hand blessed me.

Yoruba

Àyàfi tí gbogbo ọwọ́ bá bùkún mí,

120

ويخْتصني كلٌ منكُم بيدٍ.


English

And each of you singled me out with a gift.

Yoruba

Kí ìkọọkan yín yàn mí pẹ̀lú ẹ̀bun.

© , Qatru