Chapter 24

الْمَقَامَةُ الْقطيعية

161

وَالشَّيْبُ ضَيْفٌ لَهُ التَّوْقِيرُ يَا صَاحِ.


English

And gray hair is a guest to be honored, O friend.

Yoruba

Àti pé irun funfun jẹ́ àlejò tí ó yẹ kí a bọ̀wọ̀ fún, ọ̀rẹ́ mi.

162

ثُمَّ إِنَّهُ انْسَابَ انْسِيَابَ الأَيْمِ.


English

Then it flowed like the flow of a gentle stream.

Yoruba

Lẹ́yìn náà, ó ṣàn bí ṣíṣàn omi pẹlẹ́.

163

وَأَجْفَلَ إِجْفَالَ الْغَيْمِ.


English

And it fled like the fleeing of clouds.

Yoruba

Ó sì sá lọ bí ìsá àwọn àwọsánmà.

164

فَعَلِمْتُ أَنَّهُ سِرَاجُ سُرُوجٍ.


English

So I knew it was a lamp of Saruj.

Yoruba

Nítorí náà, mo mọ̀ pé ó jẹ́ fítílà ìlú Saruji.

165

وَبَدْرُ الأَدَبِ الَّذِي يَجْتَابُ الْبُرُوجَ.


English

And the full moon of literature that traverses the towers.

Yoruba

Ó si tún jẹ́ òṣùpá pípé ti ìmọ Lítíréṣọ̀ tí ó ń kọjá àwọn ilé gíga.

166

وَكَانَ قُصَارَانَا التَّحَرُّقَ لِبُعْدِهِ.


English

And our ultimate end was burning sadness for his distance.

Yoruba

Àti pé ìparí wa ni jẹ iná ìbànújẹ láti ìjìnnà rẹ̀.

167

و التفرق من بعده.


English

And separation after him.

Yoruba

Àtí ìpínyà lẹyìn rẹ.

© , Qatru