Chapter 24

الْمَقَامَةُ الْقطيعية

131

وعجِبنا.


English

And we were amazed.

Yoruba

A sì ṣe iyàlẹ́nu.

132

إذْ أُجِبنا.


English

When we were answered.

Yoruba

Nigbati wọn dáhùn wa.

133

وندِمنا.


English

And we regretted.

Yoruba

Asi ṣe abamọ.

134

على ما ند مِنا.


English

For what that has leaked out from us.

Yoruba

Fún ohun tí ì bọ́ sọ́nu lọwọ́ wá.

135

وأخذْنا نعتذِر إليهِ اعتِذار الأكْياس.


English

And we began to apologize to him like the wise.

Yoruba

A wá bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀bẹ̀ sí i bí àwọn ọlọ́gbọ́n.

136

ونعرِض عليهِ ارتِضاع الكاس.


English

And we offered him to drink from the cup of alcohol.

Yoruba

A wá ṣe apọnle fún un láti mu nínú àgọ́ ẹmu.

137

فقالَ: مأرب لا حفاوةٌ.


English

He said: A goal without hospitality.

Yoruba

Ó sọ pé: Bùkáàta láìsí ìtẹ́wọ́gbà.

138

ومشرب لمْ يبق له عندي حلاوةٌ.


English

And a drink that no longer has sweetness for me.

Yoruba

Ati ohun mímu tí kò ní àdùn mọ́ fún mi.

139

فأطَلْنا مراودته.


English

So we prolonged our persuasion.

Yoruba

Nítorí náà, a tẹ̀ síwájú nínú ìtẹ̀wọ́gbà wa.

140

ووالَينا معاودته.


English

And we continued our attempts.

Yoruba

A sì ń tẹ̀ síwájú nínú ìgbìyànjú wa.

© , Qatru