Chapter 13

الْمَقَامَةُ الْبَغْدَادِيَّةُ

21

وتِلْوِي من ترونَ عينه فُراره.


English

And this that's following me, that you're seeing, his eye is his data.

Yoruba

Ati pe èyí tí ń tẹ̀lé mí, tí ẹyín ń wò yìí, ojú rẹ̀ ní ìwádìí nípa rẹ.

22

وترجمانه اصفِراره.


English

And his translator is his paleness.

Yoruba

Ati pe olùtúmọ̀ rẹ̀ ni ìwọ̀ rẹ̀.

23

قُصوى بِغيةِ أحدِهِم ثُردةٌ.


English

The utmost desire of one of them is a crumb.

Yoruba

Papin ìfẹ́ ọ̀kan nínú wọn ni àjẹkù.

24

وقُصارى أمنِيتِه بردةٌ.


English

And the end of his wish is a cloak.

Yoruba

Ati pe ìparí ìfẹ́ rẹ̀ ni aṣọ.

25

وكنت آلَيت أنْ لا أبذُلَ الحُر.


English

And I swore not to put my cheek to shame

Yoruba

Ati pe mo búra pé mi ò ní fi ẹkẹ mí kán àbùkù

26

إلا للحر.


English

Except to the noble

Yoruba

Ayafi fún ọmọlúwàbí

27

ولو أني مت من الضر.


English

Even if I die from harm.

Yoruba

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo kú nítorí ipọnju.

28

وقد ناجتني القَرونةُ.


English

And the soul whispered to me.

Yoruba

Ati pe ẹ̀mí mí bami sọ̀rọ̀,

29

بأنْ توجد عندكُم المَعونةُ.


English

That help is found with you.

Yoruba

Wí pé ìrànlọ́wọ́ wà pẹ̀lú yín.

30

وآذنتني فِراسةُ الحوباء.


English

And the intuition of the wise informed me.

Yoruba

Ati pe ìmọ̀ràn ti ọlọ́gbọ́n sọ fún mi.

© , Qatru