And you will imagined a garden that have germinated.
Ìwọ́ yóò sì rò pé ọgbà kán ti nà ró.
This, then his dehydration is small
Èyí, lẹ́yìn náà, Ọ́gbẹ́lẹ̀ rẹ mọ níwọn.
And his strength is a loan.
Agbara rẹ̀ jẹ́ gbèsè.
And his dawn is dusk.
Àárọ̀ rẹ̀ jẹ́ ìròlẹ́.
And his garment is worn out.
Àṣọ rẹ̀ ti ṣá.
And he was anxious about the intrusion of an oppressor moneylender.
Ó sì ń bẹ̀ru nípa ìwọlé ẹni tí a jẹ́ ní gbèsè tí Ó sì tún jẹ alabosi.
Who urges him with a binding right.
Tí ó ń gbá a níyànjú nípa ẹ̀tọ́ tí ó jẹ́ dandan.
But if our master can mercifully stop him from me, with the gifts in his hand,
Nítorí tí Aṣíwájú wa, bá lè ṣe aanu fún mí làti kọ̀ fún pẹlú àwọn ẹ̀bùn ọwọ́ rẹ̀,
He would have adorned himself with surpassing glory.
Yóò fi ògo tí ó ga ju gbogbo lọ ṣe ara rẹ̀ lọ̀ṣọ́.
And he would have returned with the reward of freeing me from bondage.
Ó sì padà pẹ̀lú èrè ìdásílẹ̀ kúrò nínú ìdè.