Chapter 30

الْمَقَامَةُ الصُّورِيَّةُ

31

فبرز حينئذٍ شيخ قد أمالَ الملَوانِ قامته.


English

Then emerged an elder whose stature had been bent by days and nights (time).

Yoruba

Nígbà náà ni àgbàlagbà kan tí àkókò ojúmọ́ pẹlú aṣálẹ ti tẹ́ ẹ̀ mọ́lẹ̀ jáde.

32

ونور الفَتيانِ ثَغامته.


English

Whose mornings and evenings had lighted his (Thugamat) face.

Yoruba

Ti owurọ pẹlu irọlẹ ti tán ìmọ́lẹ̀ sí ojú rẹ̀.

33

فتباشرتِ الجماعةُ بإقْبالِه.ِ


English

The group rejoiced at his arrival.

Yoruba

Ẹgbẹ́ náà yọ̀ nígbà tí ó dé.

34

وتبادرت الى استِقبالِه.ِ


English

And hurried to greet him.

Yoruba

Wọ́n sì yara láti kí í.

35

فلما جلَس على زربِيتِه.ِ


English

When he sat on his mat.

Yoruba

Nígbà tí ó jókòó sórí ẹní rẹ̀.

36

وسكنتِ الضوضاءُ لهيبتِه.ِ


English

The noise quieted due to his presence.

Yoruba

Àríyá náà dákẹ́ nítorí wìwà rẹ̀ láàyè náà.

37

ازدلَف الى مسندِه.ِ


English

He approached his seat.

Yoruba

Ó sún mọ́ àga rẹ̀.

38

ومسح سبلَته بيده.ِ


English

And stroked his beard with his hand.

Yoruba

Ó sì fọwọ́ rẹ̀ pá irungbọ̀n rẹ̀.

39

ثمّ قال: الحمد للهِ المُبتدِئِ بالإفْضال.ِ


English

Then he said: Praise be to Allah, the initiator of grace.

Yoruba

Lẹ́yìn náà ó sọ pé: Ògo ni fún Allah, ẹni tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹlú ọ̀lá.

40

المُبتدِعِ للنوال.ِ


English

The creator of blessings.

Yoruba

Ẹni tí ó dá àánú.

© , Qatru