Chapter 30

الْمَقَامَةُ الصُّورِيَّةُ

71

وقد بذلَ لها من الصداقِ شلاّقاً وعكّازاً.


English

He offered her a dowry of a sack and a staff.

Yoruba

Ó fún un ní ẹ̀bùn ìgbéyàwó ni tí àpò àti ọ̀pá.

72

وصِقاعاً وكزازاً.


English

Together with a scarf and a jar.

Yoruba

Pẹlú ìbòrí àti kòndò omí

73

فأنكِحوه إنكاح مثلِه.ِ


English

So marry him off with a marriage like his.

Yoruba

Nítorí náà, fún un ní ìgbéyàwó bí ti ẹ̀.

74

وصِلوا حبلَكُم بحبلِه.ِ


English

And join your rope with his rope.

Yoruba

Ẹ so okun yin pọ̀ mọ́ ti ẹ̀.

75

وإنْ خِفْتم عيلَةً فسوف يغنيكُم االلهُ من فضلِه.ِ


English

And if you fear poverty, Allah will enrich you from His bounty.

Yoruba

Bí ẹ bá bẹ̀rù ìyà, Allah yóò fún yín ní ọlá láti inú àánú rẹ̀.

76

أقولُ قولي وأستغفِر االلهَ العظيم لي ولكُم.


English

I say my words and seek Allah's forgiveness for myself and for you.

Yoruba

Mo sọ ọ̀rọ̀ mi, mo sì bẹ̀ Allah fún ìdáríjì fún ara mi àti fún yín.

77

وأسألُه أن يكثِر في المَصاطِبِ نسلَكُم.


English

And I ask Him to increase your offspring on the benches.

Yoruba

Mo sì bẹ̀ ẹ̀ pé kí ó pọ̀ àwọn ọmọ yín lórí àpótí.

78

ويحرس من المَعاطِبِ شمْلَكُم.


English

And to protect your unity from harm.

Yoruba

Àti láti dáàbò bo ìṣọ̀kan yín kúrò nínú ìjàmbá.

79

فلما فرغَ الشيخ من خطبتِه.ِ


English

When the elder finished his sermon.

Yoruba

Nígbà tí àgbàlagbà náà parí ìwàásù rẹ̀.

80

وأبرم للختنِ عقْد خِطبتِه.ِ


English

And sealed the marriage contract and presented it to the bride's relative.

Yoruba

Ó sì fi ìwé ìgbéyàwó fún ẹbí ìyàwó náà

© , Qatru