And filled his belly like yours
Àti ẹnikẹ́ni tí ó bá kún inú rẹ̀ bí ìwọ ṣe kún inú rẹ.
Will hardly escape from debilitating indigestion.
Kò ní lè yọ kúrò nínú inú rirun tí ó ń pa èèyàn
Or destructive cholera.
Àbí àrùn kọlẹrà tí ó ń pani
So leave me alone, for God's sake, sufficiently.
Nítorí náà, fi mí sílẹ̀, pẹ̀lú amojukuro, mofi Ọlọ́run bẹ ọ,
And depart from me as long as you are well.
Kí o sì jáde kúrò lọ́dọ̀ mi pẹ̀lú àlááfíà.
By the One who gives life and causes death.
Ní orúkọ Ẹni tí ó ń yè èèyàn àti tí ó ń pa.
You have no place to stay with me!
Ìwọ kò ní ibi láti máa sun pẹ̀lú mi!
When I heard his swear,
Nígbà tí mo gbọ́ ibúra rẹ
And I tested his affliction.
Àti mo dán ìjàmbá rẹ̀ wò.
I left his house reluctantly.
Mo jáde kúrò ní ilé rẹ̀ ní àìfẹ́.