Chapter 16

الْمَقَامَةُ الْمغربية

91

رأيت صاحِب صيدِنا. هو أبو زيدِنا.


English

I saw the master of our hunt; he is our Abū Zayd.

Yoruba

Mo rí olùkọ́ wa nínú pápá; ọ̀un ni Abū Seidu wa.

92

فقلت لأصحابي: هذا الذي أشرت الى أنه إذا نطَق أصاب.


English

So I said to my companions: This is the one I mentioned who speaks correctly when he talks.

Yoruba

Nítorí náà, mo sọ fún àwọn ọ̀rẹ́ mi pé: Èyí ni ẹni tí mo sàpèjúwe pé ó máa ń sọ̀rọ̀ tó ní òtítọ́ nígbà tí ó bá ń sọ̀rọ̀.

93

وإنِ استمطِر صاب.


English

And when he seeks rain, it pours.

Yoruba

Àti tí wọ́n ba béèrè ojo rẹ, ó máa ń rọ̀ lọ́nà púpọ̀.

94

فأتلَعوا نحوه الأعناق. وأحدقوا بهِ الأحداق.


English

They craned their necks towards him and fixed their eyes upon him.

Yoruba

Wọ́n gbé ọ̀run wọn sókè sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì fi ojú wọn lé.

95

وسألوه أنْ يسامِرهم ليلَته. على أن يجبِروا عيلَته.


English

And they asked him to spend the night entertaining them, promising to provide for his family.

Yoruba

Wọ́n sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé kí ó pẹ̀lú wọn lọ́jọ́kan, wọ́n sì ṣèlérí láti tójú ẹbí rẹ̀.

96

فقال: حباً لِما أحببتم. ورحباً بكُم إذا رحبتم.


English

He said: With love for what you desire, and you are welcome whenever you welcome me.

Yoruba

Ó sọ pé: Pẹ̀lú ìfẹ́ fún ohun tí ẹ fẹ́, ẹ kú àbọ̀ nígbà gbogbo tí ẹ bá gbà mí.

97

غير أني قصدتكُم وأطْفالي يتضورونَ من الجوع.ِ


English

However, I came to you while my children are writhing from hunger.

Yoruba

Síbẹ̀, mo wá sí ọ̀dọ̀ yín nígbà tí àwọn ọmọ mi ń ṣubú fún ìbànújẹ́ nítorí ebi.

98

ويدعونَ لي بوشكِ الرجوع.ِ


English

And they are praying for my quick return.

Yoruba

Àti pé wọ́n ń gbàdúrà fún mi kí n padà kíákíá

99

وإنِ استراثوني خامرهم الطّيش. ولمْ يصف لهم العيش.


English

If they agreed that I am late, they will become restless, and their lives will no longer be peaceful.

Yoruba

Tí wọ́n bá fẹnu kò pe mo tí pẹ, wọn yóò dálè rú, àti pé ayé wọn kò ní dùn mọ́ lára wọn.

100

فدعوني لأذْهب فأسد مخمصتهم. وأُسيغَ غُصتهم.


English

So allow me to go and fill their hunger and ease their choking,

Yoruba

Nítorí náà, jẹ́ kí n lọ dí ìyàn wọn, kí n sì mú ìnira wọn rọlẹ.

© , Qatru