Chapter 16

الْمَقَامَةُ الْمغربية

11

فَلَمْ أَجْلِسْ إِلَّا لَمْحَةَ بَارِقٍ خَاطِفٍ أَوْ نَغْبَةَ طَائِرٍ خَائِفٍ.


English

I did not sit except for a fleeting moment or a sip of a fearful bird.

Yoruba

Mi ò jókòó bí kò ṣe fún ìṣẹ́jú kan tàbí gẹgẹ bí ìyára mú omi ẹyẹ tí ó bẹ̀rù kan.

12

حَتَّى غَشِيَنَا جَوَابٌ عَلَى عَاتِقِهِ جِرَابٌ.


English

Until a man with a bag on his shoulder approached us.

Yoruba

Títí tí ọkùnrin kan pẹ̀lú àpò kan lórí ejika rẹ̀ fi wá sí ọdọ wa.

13

فَحَيَّانَا بِالْكَلِمَتَيْنِ وَحَيَّا الْمَسْجِدَ بِالتَّسْلِيمَتَيْنِ.


English

He greeted us with two words and greeted the mosque with two salutations (Rak'ats).

Yoruba

Ó kí wa pẹ̀lú ọ̀rọ̀ méjì, ó sì kí mọ́ṣáláàsì náà pẹ̀lú kiki (Irun nafila) méjì.

14

ثُمَّ قَالَ: يَا أُولِي الْأَلْبَابِ وَالْفَضْلِ اللُّبَابِ.


English

Then he said: "O people of intellect and pure virtue."

Yoruba

Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: "Ẹ̀yin ènìyàn ọgbọ́n àti ìwà rere mímọ́."

15

أَمَا تَعْلَمُونَ أَنَّ أَنْفَسَ الْقُرُبَاتِ تَنْفِيسُ الْكُرُبَاتِ؟


English

Do you not know that the most precious acts of closeness are relieving distress?

Yoruba

Ṣé ẹ kò mọ̀ pé àwọn iṣẹ́ ìsúnmọ́ tó níyelórí jù ni láti yọ àwọn ìbànújẹ́ kúrò?

16

وَأَمْتَنَ أَسْبَابِ النَّجَاةِ مُؤَاسَاةُ ذَوِي الْحَاجَاتِ؟


English

And the strongest reasons for salvation are comforting those in need?

Yoruba

Àti pé àwọn ìdí tó lágbára jù fún ìgbàlà ni láti tù àwọn tó ní bùkátà nínú?

17

وَإِنِّي وَمَنْ أَحَلَّنِي سَاحَتَكُمْ.


English

Now, by Him who brought me to your courtyard.

Yoruba

Dájúdájú emí, mo búra ní orúkọ Oun tí ó mú mi wá sí àgbàlá yín.

18

وَأَتَاحَ لِيَ اسْتِمَاحَتَكُمْ.


English

And granted me your generosity.

Yoruba

Ó sì fún mi ní àánú yín.

19

لشَرِيد مَحِل قَاصٍ.


English

I am a wandering, destitute, distant one.

Yoruba

Mo tí jẹ ẹni tí ó ń rìn kiri, tí ó sì jẹ́ aláìní, tí ó jìnnà.

20

وَبَرِيد صِبْيَةٍ خِمَاصٍ.


English

And a messenger of hungry children.

Yoruba

Àti ìránṣẹ́ àwọn ọmọ tí ń ebi ń pá,

© , Qatru