Chapter 16

الْمَقَامَةُ الْمغربية

81

فاقوا الأنام فضائِلاً مأثورةً وفواضِلا.


English

They surpassed mankind with inherited virtues and noble qualities.

Yoruba

Wọ́n jù àwọn ènìyàn lọ nípa àwọn ìwà rere tí wọ́n jogún rẹ àti àwọn ìwà ọlá.

82

حاورتُهم فوجدتُ سح باناً لديهِم باقِلا.


English

I conversed with them and found that Sahbān in their midst, will be Bakil

Yoruba

Mo bá wọn sọ̀rọ̀, mo sì rí pé ti Sahbān ba wá láàrin wọn,yóò díì Bakilu

83

وحللْتُ فيهِم سائِلاً فلَقيتُ جوداً سائِلا.


English

I arrived among them as a seeker and found generous pouring!

Yoruba

Mo dé àárín wọn bí ẹnìkan tó béèrè fún àánú, mo sì rí ẹbun tí ó ń ṣàn!

84

أقسمتُ لو كان الكِرا م حياً لكانوا وابِلا.


English

I swore that if the generous were small rain, those are definitely flood

Yoruba

Mo búra pé bí ọlá bá ojo kékeré, wọ́n yóò jẹ agbanla omi (ojo jàjafá).

85

ثم خطا قِيد رمحينِ. وعاد مستعيذاً من الحَينِ.


English

Then he took two spear-length steps and returned seeking refuge from death

Yoruba

Lẹ́yìn náà, ó gbésẹ̀ niwọn ọfà méjì, ó sì padà láti wá ààbò lọ́wọ́ iku

86

وقال: يا عِز من عدِم الآلَ. وكَنز من سلِب المالَ.


English

And he said: O honor for those who lack lineage, and treasure for those who have lost wealth.

Yoruba

Ó sọ pé: Ẹ ọlá fún àwọn tí kò ní ìran, àti ìṣúra fún àwọn tí wọ́n sọnù nínú òwò.

87

إن الغاسِق قد وقَب. ووجه المحجةِ قدِ انتقَب.


English

The darkness has enveloped, and the clear path has become obscured.

Yoruba

Òkùnkùn ti wọ̀, ọ̀nà tó hàn náà sì ti ń dì jú

88

وبيني وبين كِني ليلٌ دامِس. وطريق طامِس.


English

Between me and my goal is a dark night and a path that is lost.

Yoruba

Láàrin èmi àti ibi tí mo ń lọ ni òru tí ó ṣokunkun àti ọ̀nà tí ó ti pàrẹ.

89

فهلْ من مِصباحٍ يؤمِنني العِثار. ويبين ليَ الآثار؟


English

Is there a lamp that can protect me from stumbling and show me the way?

Yoruba

Ṣé kòsí àtúpà kan tí yóò lè dáàbò bo mí kúrò nínú ìkọsẹ̀ àti tí yóò fún mi ní ìran ọ̀nà?

90

قال: فلما جِيء بالمُلتمس.ِ وجلّى الوجوه ضوءُ القبس.ِ


English

He said: When the request was granted, and the light of the torch revealed the faces.

Yoruba

Ó sọ pé: Nígbà tí a bá wá ohun ti o béèrè náà, ti ìmọlẹ̀ fitilà sì ṣàfihàn àwọn ojú náà.

© , Qatru