Chapter 18

الْمَقَامَةُ السنجارية

11

وسفَر عن مرأًى وسيمٍ.


English

And a beautiful sight was revealed.

Yoruba

àwòrán ẹlẹ́wà kan sì farahàn

12

وأرجِ نسيمٍ.


English

And fragrant of the breeze

Yoruba

Àti òórùn afẹ́fẹ́

13

فلما اضطَرمت بمحضرِهِ الشهواتِ.


English

When pleaaures flared up in his presence.

Yoruba

Nígbà tí ìgbádùn ti gbóná níwájú rẹ̀.

14

وقرِمت الى مخْبرِهِ اللّهواتِ.


English

And the tongues longed for his news,

Yoruba

Àti pé awon ahọ̀n náà ń fẹ́ tọ ìròyìn rẹ̀ wo,

15

وشارف أنْ تشن على سِربِهِ الغاراتِ.


English

And raids were about to be launched on his group.

Yoruba

Àti pé wọ́n fẹrẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìkógun sí ẹgbẹ́ rẹ̀.

16

وينادى عند نهْيِه:ِ يا للثّاراتِ!


English

And it was called out at his prohibition: Oh, for revenge!

Yoruba

O kigbé jáde nígbà tí o kọ fún: Ò ya o, fún ìgba esan!

17

نشز أبو زيدٍ كالمجنونِ.


English

Abu Zayd stood up like the one insane,

Yoruba

Baba Seidu dìde bí òní gangan gan-an

18

وتباعد عنه تباعد الضب من النونِ.


English

And he distanced himself like a lizard from a fish.

Yoruba

Ó sì yà ara rẹ̀ kúrò bí alangba kúrò lọwọ ẹja.

19

فراودناه على أن يعودِ.


English

We persuaded him to return.

Yoruba

A gbìyànjú láti dá a lóhùn láti padà.

20

وأنْ لا يكونَ كقُدارٍ في ثمودِ.


English

And not to be like Qudar in Thamud.

Yoruba

Àti pé kó má ṣe bí kudaru nínú ilu Samudu

© , Qatru