Chapter 18

الْمَقَامَةُ السنجارية

21

فقال: والذي ينشر الأموات من الرجامِ.


English

He said: "By the One who resurrects the dead from the graves."

Yoruba

Ó ní: Nípa Ẹni tí ó jí àwọn òkú dìde láti inú ibojì.

22

لا عدت دونَ رفْعِ الجامِ.


English

I will not return without lifting the goblet,

Yoruba

Èmi kì yóò padà láìsí gbígbé ìfé (oni gíláàsì) kúrò,

23

فلم نجِد بداً من تألُّفِه.


English

So we found no choice but to cooperate with him.

Yoruba

Nítorí náà, a kò rí ibuyẹsí láti bàa ṣe

24

وإبرارِ حلِفِه.


English

And to fulfill his oath.

Yoruba

Àti láti mú ìbúra rẹ̀ ṣẹ.

25

فأشلْناه والعقولُ معه شائِلَةٌ.


English

So we lifted him and the minds were lifted with him.

Yoruba

Nítorí náà, a gbé e dìde àti pé àwọn ọkàn náà dìde pẹ̀lú rẹ̀.

26

والدموع علَيهِ سائِلَةٌ.


English

And tears were flowing for him.

Yoruba

Àti pé àwọn omijé ń ṣàn fún un.

27

فلما فاءَ الى مجثمِه.


English

When he returned to his resting place.

Yoruba

Nígbà tí ó padà sí ibi ìsinmi rẹ̀.

28

وخلَص من مأثَمِه.


English

And was freed from his sin.

Yoruba

Tí o sì rí òmìnira kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

29

سألناه لمَ قام.


English

We asked him why he stood up.

Yoruba

A béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ ìdí tí ó fi dìde.

30

ولأي معنى استرفَع الجام؟


English

And for what reason did he lift the goblet?

Yoruba

Àti fún ìdí wo ni ó gbé ìfé náà soke?

© , Qatru