Chapter 22

الْمَقَامَةُ الْفُرَاتِيَّةُ

111

وإعنات فيما ينشا.


English

And hardship in what is created.

Yoruba

Àti pé ìṣòro ń bẹ nínú ohun tí a dá.

112

حتى يغشى. ويرشى.


English

Until it's overwhelmed and bribed.

Yoruba

Títí tí a fí borí rẹ tí a sí fún ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

113

إلا الذين آمنوا وعمِلوا الصالِحاتِ وقَليلٌ ما هم.


English

Except for those who believe and do good deeds, and few are they.

Yoruba

Àyàfi àwọn tí ó ní ìgbàgbọ́ àti àwọn tí ó ṣe iṣẹ́ rere, tí wọ́n kò sì pọ́ rárá.

114

قال الحارِثُ بن همّام:ٍ فلما أمتع الأسماع. بما راق وراع.


English

Al-Harith ibn Hammam said: When he delighted the ears with what was pleasing and terrifying.

Yoruba

Hárìsù ọ̀mọ̀ Hammam sọ pé: Nígbà tí ó tí jẹ kí àwọn etí gbádùn pẹlú ọ̀rọ̀ rẹ tí o dun tí o sì ṣe èèmọ.

115

استنسبناه فاستراب. وأبى الانتِساب. ولو وجد منساباً لانساب.


English

We sought his lineage, but he doubted and refused affiliation. Had he found an escape, he would have entered.

Yoruba

Àwa bèèrè nípa ìrán rẹ̀, ṣùgbọ́n ó ṣiyè méjì ó sì kọ ṣe ìbátan. Bí ó bá ti rí iho kan, yóò kó sí ìbẹ̀.

116

فحصلْت من لبسِهِ على غُمة.ٍ حتى ادكَرت بعد أمة.ٍ


English

So I was in confusion because of his ambiguity until I remembered after a long time.

Yoruba

Nigba naa, nitori iro pipa re, mo wa ninu ibanuje , títí tí mo fi rántí lẹ́yìn òpòlopò ọdún.

117

فقُلْت: والذي سخر الفلَك الدوار. والفُلْك السيار.


English

So I said: By the One who made the rotating heavens and the moving ships.

Yoruba

Nítorí náà, mo sọ pé: Ní orukọ́ Ẹni tí ó dá àwọn ọ̀run tó ń yí, àti àwọn ọkọ̀ tó ń lọ.

118

إني لأجِد ريح أبي زيد.ٍ وإنْ كنت أعهده ذا رواءٍ وأيد.ٍ


English

I surely sense the scent of Abu Zayd, though I remember him as one of splendor and strength.

Yoruba

O dájú pé mo ń gbóòrùn Baba Seidu, bó tilẹ̀ jẹ́ pé mo rántí rẹ sí ẹ̀lẹ́wà àti alagbára.

119

فتبسم ضاحِكاً من قولي. وقال: أنا هو على استِحالَةِ حالي وحولي.


English

He smiled and laughed at my words and said: It is I, despite the transformation of my condition and surroundings.

Yoruba

Ó rẹ́rin pẹ̀lú èrín pẹ̀lú ohun tí mo sọ, ó sọ pé: Èmi ni, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àyíká àti ìbẹ̀rẹ̀ mi ti yí padà.

120

فقلت لأصحابي: هذا الذي لا يفْرى فرِيه. ولا يبارى عبقَريه.


English

So I said to my companions: This is the one whose achievements cannot be surpassed, whose genius is unparalleled.

Yoruba

Nítorí náà, mo sọ fún àwọn ẹ̀gbọ́n mi: Èyí ni ẹni tí a kò le ṣe irú ìgbìyànjú rẹ, ẹni tí òye rẹ̀ kò ni ẹlẹgbẹ́.

© , Qatru