Chapter 22

الْمَقَامَةُ الْفُرَاتِيَّةُ

61

وهُوَ البَشِيرُ والنَذِير.


English

He is the bringer of good news and warnings.

Yoruba

Ó jẹ́ òní iró ìdùnu àti ìkìlọ.

62

والشَفِيعُ والسَفِير.


English

The intercessor and the ambassador.

Yoruba

Olùṣìpẹ̀ àti aṣojú.

63

بهِ تُسْتَخْلَصُ الصَيَاصِي.


English

With it, strongholds are taken.

Yoruba

Pẹ̀lú rẹ̀ ni a ń gbà ilé ìsó agbára.

64

وتُمَلَّكُ النَوَاصِي.


English

And forelocks are seized.

Yoruba

Wọn sì máa ń kápá awọn ọtá.

65

ويُقْتَادُ العَاصِي.


English

The rebellious is subdued.

Yoruba

Wọn sì máa ń darí ẹ̀lẹ̀ṣẹ (fìyà jẹ).

66

ويُسْتَدْنَى القَاصِي.


English

And the distant is brought near.

Yoruba

Ẹni tó jìnnà ni a ń mú wọlé.

67

وصَاحِبُهُ بَرِيءٌ مِن التَبِعَاتِ.


English

Its owner is free from burdens.

Yoruba

Olówó rẹ là kúrò nínú gbogbo ẹ̀rù bùkáàtà.

68

آمِن كَيْد السُعَاة.


English

Safe from the plotting of conspirators.

Yoruba

Òní ìfọ̀kànbálẹ̀ kúrò lọwọ ète abanijẹ́.

69

مُقَرَّظٌ بَيْنَ الجَمَاعَاتِ.


English

Praised among groups.

Yoruba

Ó jẹ́ ẹni tí a máa ń fi yín fún láàrin àwọn ẹgbẹ́.

70

غَيْر مُعَرَّضٍ لِنَظْمِ الجِمَاعَاتِ.


English

Not subjected to the designing of records.

Yoruba

Kò sí jẹ́ èèyàn tí wọn tí sí ṣíṣe àkọsílẹ ẹgbẹ́.

© , Qatru