Chapter 22

الْمَقَامَةُ الْفُرَاتِيَّةُ

51

وَأَسَاطِيرُ البَلَاغَةِ تُنْسَخُ لِتُدْرَس.


English

And the tales of eloquence are copied to be studied.

Yoruba

Àwọn àló onímọ̀ràn ni a ṣe ẹda rẹ̀ fún ìkọ́ni.

52

ودَسَاتِيرُ الحُسْبَانَاتِ تُنْسَخُ وَتُدْرَس.


English

And the manuals of accounts are deleted and scrapped off.

Yoruba

Àwọn ìwé àkọsílẹ̀ ìṣirò ni wọn má ń yọ, tí wọn sì má ń paarẹ.

53

وَالمُنْشِئُ جُهَيْنَةُ الأَخْبَار.


English

The prose writer is the source of news.

Yoruba

Onkọ̀wé àròkọ ni orísun ìròyìn.

54

وحَقِيبَةُ الأَسْرَار.


English

And the bearer of secrets.

Yoruba

Àti àpò ìkọ̀kọ̀.

55

ونَجِي العُظَمَاء.


English

And the confidant of the great.

Yoruba

Àti ọ̀rẹ́ àwọn olókìkí.

56

وكَبِير النُدَمَاء.


English

And the chief of companions.

Yoruba

Àti olórí àwọn ẹlẹgbẹ́.

57

وقَلَمُهُ لِسَانُ الدَّوْلَة.


English

His pen is the tongue of the state.

Yoruba

Kàlámù rẹ̀ jẹ́ èdè fún ìjọba.

58

وفَارِسُ الجَوْلَة.


English

And the knight of the round.

Yoruba

Àti ọdẹ nípàdé.

59

ولُقْمَانُ الحِكْمَة.


English

And the sage of wisdom.

Yoruba

Àti Lukumọ́nù ọlọ́gbọn.

60

وتَرجُمَانُ الهِمَّة.


English

And the interpreter of determination.

Yoruba

Àti Òngbìfọ̀ agbiyelé.

© , Qatru