الْمَقَامَةُ الدِّينَارِيَّةُ

عَرَبِيَّة : وقال: أنجز حر ما وعد.

English: And said: A noble one fulfills what he promises,

Yoruba: Ó sì wí pé: Ọmoluabi a máa mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ,

عَرَبِيَّة : وسح خالٌ إذ رعد.

English: And the cloud rains when it thunders.

Yoruba: esujo a sì máa rọ̀jò nígbà tí ó bá sán àrá.

عَرَبِيَّة : فنبذْت الدينار إليه.ِ

English: So I tossed the dinar to him,

Yoruba: Nítorí náà mo jù dínárì náà fún un,

عَرَبِيَّة : وقلت: خذْه غير مأسوفٍ علَيه.ِ

English: And said: Take it without regret,

Yoruba: Mo sì wí pé: Gbà á láìsí ìbànújẹ́,

عَرَبِيَّة : فوضعه في فيه.ِ

English: So he put it in his mouth,

Yoruba: Ó sì fi sí ẹnu rẹ̀,

عَرَبِيَّة : وقال: بارِك اللهم فيهِ!

English: And said: May Allah bless it!

Yoruba: Ó sì wí pé: Kí Ọlọ́hun bùkún un!

عَرَبِيَّة : ثمّ شمّر للانثِناء.

English: Then he prepared to leave,

Yoruba: Lẹ́yìn náà ó múra láti lọ,

عَرَبِيَّة : بعد توفِيةِ الثّناء.

English: After completing his praise.

Yoruba: Lẹ́yìn tí ó ti parí ìyìn rẹ̀.

عَرَبِيَّة : فَنَشَأَتْ لِي مِنْ فُكَاهَتِهِ نَشْوَةُ غَرَامٍ.

English: From his humor arose in me a passion's intoxication,

Yoruba: Láti inú ẹ̀rín rẹ̀ ni ìfẹ́ àtọwọ́dá dìde nínú mi,

عَرَبِيَّة : سَهَّلَتْ عَلَيَّ ائْتِنَافَ اغْتِرَامٍ.

English: That made it easy for me to resume fascination.

Yoruba: Èyí tó mú kí ó rọrùn fún mi láti tún bẹ̀rẹ̀ ìfẹ́.

© , Qatru